[Lyrics] Asa – Grateful Lyrics

Hit ground running
0

 [Lyrics] Asa – Grateful Lyrics

Lyrics
Era ilẹ’, era ilẹ’, wọn yìn Bàbá l’òkè
‘Yanrìn, òkun, ‘yanrìn, òkun, wọn yìn Bàbá l’òkè
Ẹranko ilé, ẹranko igbó, wọn yín Bàbá l’òkè
Àwọn aláìní, àwọn tán tí ní, wọn yìn Bàbá l’òkè
Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe’yán
Kò tó mọ pé Bàbá ń bẹ l’òkè
Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe’yán
Kò tó mọ pé loótọ’ ò ńbẹ l’òkè
You don’t have to wait ’til you feel the pain
You can start right now
It’s not too late
It’s not too late to be grateful!
Ah, ah, uhm
Ah, ah, ah, ah-ah, ah
Hmm-mmm
Era ilẹ’, era ilẹ’, wọn yìn Bàbá l’òkè
‘Yanrìn òkun, ‘yanrìn òkun, wọn yìn Bàbá l’òkè
Pé mo wà láyé, mo wà láàyè
Gbogbo òun tí mò ní, má fí yìn ò lógo
Believe this world a better place
Ah-ah-ah, eh-eh
Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe’yàn
Kò tó mọ pé Bàbá ńbẹ l’òkè (okay)
Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe’yàn
Kò tó mọ pé loótọ’ ò ńbẹ l’òkè
You don’t have to wait ’til you feel the pain
You can start right now (okay)
It’s not too late (it’s not too late)
It’s not too late to be grateful (yes)
Ahh
O rí bí mo ṣe ńf’ẹgbẹ yìn Bàbá
Ta, du-ba, du-ba (hey)
Ta, du-ba, du-bu (hey)
Ba, du-ba, du-ba (hey)
Da, du-da, du-bu (hey)
It’s not too late
Uhh-uh-uh, eh (hey)
Ta, du-ba, du-bu
(Yeah-yeah, oh, that’s right)


Share [Lyrics] Asa – Grateful Lyrics with others on social media;

Post a Comment

0Comments
Post a Comment (0)
To Top