[Lyrics] Qdot – Eleda Lyrics

0

Lyrics
Iji ra ale, aleka malaika (aleka malaika)
Ijimi ma serifu malaika mi
Qdot lórúko mí
Bàbá lókè má fí mí sí one corner
Àgbà dé kàn tó gb’ohùn Rolling Dollar
Má ṣe mí l’Aboki oníṣẹ́
Bàbá, dàkún, ṣé mí lọmọ aláṣelà
Ṣébí, alapata lo lọ’run ẹran
Má sọ pé ó dán ìgbàgbọ’ mí wo
K’ayé má bá tú mí l’aṣọ wo
Ọmọ Adeboye ó gbọ’dọ’ wọ ẹkùn ègùn
Ọmọ alapata ó gbọ’dọ’ jẹ egungun
Ṣé mí ní dá rocha, má ṣe mí l’alakisa
Ọlọrun àwọn Ọlọrun
Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani (mo gbé oh)
Mó tí fití Késárì fún Késárì (fún Késárì)
Mó tí lo church, mó tí lọ mosa’asi
Àgbàlagbà mo’ mí dáa lọ yí
Ẹlẹ’dà má sún (Ẹlẹda mí má sún)
Ẹlẹda má sún (Ẹlẹda má sún)
Ẹlẹda mí má sún (woah)
Mó gbàgbọ’ pé ọmọ Ọlọrun ní Jésù
Mó gbàgbọ’ pé òjíṣẹ́ rẹ l’Anọbi (sallallahu ‘alayhi wa sallam)
Ọlọrun ó ṣebì èèyàn lo ń ṣe’ka
T’ayé bà bínú wọn má ní kí Eyimba na Barça pàá oh
Qudus ó mọ pé ogún láyé oh
Ń bá rà ìbọn, ń bá rà ‘dá
Àwọn tẹ gbà’yé fún, kó ṣ’ojú àyé
K’oma f’áyé mí t’afala
Àdàbà tí ko lé fo mọ, oh-ohh
Ọmọ aráyé lo tún dáa
Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani
Mó tí fití Késárì fún Késárì
Mó tí lo church, mó tí lọ mosa’asi
Àgbàlagbà mo’ mí dáa lọ yí
Ẹlẹda má sún (ara eli Mikail)
Ẹlẹda má sún (ara ‘ba malaika fali mi)
Ẹlẹda mí má sún (e li kulu modá bara n kadu ‘lifa)
Ẹlẹda má sún (ẹ’rí ń bẹ lókè Agelu)
Ẹlẹda mí má sún (sata ta ulehu)
Ẹlẹda má sún (orí mí jọọ-)
Mà jẹ ń d’àgbàya kín tó d’olówó oh-oh
Ẹ’dá mí jọọ (orí mí jọọ oh)
Alola fari gi noti, seri moda fa’yallahu (fa’yallahu)
Bàbá dá mí lóhùn (dá mí lóhùn)
Àgbà dé eee (àgbà dée)
Àgbà dé kàn tó gb’ohùn Rolling Dollar
(Yeah, ayy-ayy-ayy)
(Bàbá dá mí lóhùn)
Fali uli faki ilaina (Ẹlẹda má sún)
(Yeah, who’s here?)


Share [Lyrics] Qdot – Eleda Lyrics with others on social media;

Post a Comment

0Comments
Post a Comment (0)
To Top