[Lyrics] Qdot – Ayedun Lyrics

0

Lyrics
Seribumi
Seribumi elédè kewu (Shocker lo ṣe beat)
Iji ra
Qdot lórúkọ tèmi
Qdot lórúko mí oohh, eh-oh
Àyé là bowó (ayé là bowó)
Àyé là má fí silẹ lọ (silẹ lọ)
Ayànmọ pẹ’lú kádàrá wọn yàtọ’ sírà wọn
Òní k’ajá má gbé nílé, ó yàn kinihun sínú igbó
T’óbá lówó ló d’àwo ilé àyé (yeah oh, e eh-eh)
O lówó lọwọ, ó d’ẹrù àyé (ahn-ahn, kílódé?)
Olówó l’ayé má fún láyè, torí olówó l’ayé fẹ rí
Ẹlẹ’dàá mí o ṣemí lẹni àyé fẹ rí (Ẹlẹ’dà mí oh-ohh)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ero mí tó ń jò, tó ń jo lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọ’run lóbá mí ṣe (yay)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọ’run lóbá mí ṣe
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ọ’rẹ’, wo, owó lafi ń ṣe ilé àyé
Ìwà ló má fi ń ṣe ọrùn (fi ń ṣe ọ’run)
Bóṣé lówó tó o, lomá gbádùn òyìnbó to
Lomú Davido ọmọ Bàbá Olówó pariwo p’owó ní kókó
Money good ohh, ohh
Poverty no sweet oh, my brother
T’óbá lówó lo d’àwo ilé àyé (ooh, ooh, yeah-yeah-yeah)
Ó lówó lọwọ ó d’ẹrù àyé (ahn-ahn, kílódé o?)
Olówó láyé má fún láyè, torí olówó láyé fẹ rí
Ẹlẹ’dàá mí oh, ṣemí lẹni àyé fẹ rí
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi (ayy-ayy, oh)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọrun lóbá mí ṣe
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọrun lóbá mí ṣe (bá mí ṣe)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Àyé dùn (àyé dùn jẹ jù’yà lo)
Àyé yí dùn (àyé dùn jẹ jù’yà lo)
Orí ṣemí l’olówó àyé (àyé dùn jẹ jù’yà lo)
Bí tí Wasiu Ayinde o (àyé dùn jẹ jù’yà lo)
Bí tí K1 De Ultimate (àyé dùn jẹ jù’yà lo)
Shout out to Mayegun gbogbo ilé Yorùbá
Yeah, who’s here?


Share [Lyrics] Qdot – Ayedun Lyrics with others on social media;

Post a Comment

0Comments
Post a Comment (0)
To Top